ỌWỌ TẸ ÀWỌN AJINIGBE MEJI NILUU Ọ̀WỌ̀

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 1 окт 2024
  • TWO KIDNAPPERS ARRESTED IN OWO BY AMOTEKUN

Комментарии • 10

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 4 дня назад +3

    Gbogbo eyin akikanju Olohun a ma wa pelu gbogbo yin, Olohun ama dabo boyin

  • @olarindefolashade4405
    @olarindefolashade4405 4 дня назад +1

    Olorun amafun yi se ni agbara olorun

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 4 дня назад

    Kudos to the Amotekun God almighty will continue to expose them all

  • @rachelyusuf9246
    @rachelyusuf9246 4 дня назад

    Gbogbo awon ti o tun ku ni owo awon Amotekun ma a te lagbara Olorun. E ku ise o Amotekun Olorun yo ma a fun yin se

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy2002 4 дня назад

    E ku ise olorun atunbo maa fun yin ni agbara amin

  • @odunolaalli6773
    @odunolaalli6773 4 дня назад

    E ku ise takun takun, oluwa a ma fun yin se

  • @goldenroyal7351
    @goldenroyal7351 4 дня назад

    Teba mun awan odaran ajini gbe emawa keyin wan si Camera ti ebamun awan omo teunro pe boya wan se aburu kan tabi wano se aburu ko dara to ejeki ama aroju wan now ti wan bawa salo bawoni ase fe ran agbofinro lówó latiri wan mun pada

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 4 дня назад

    Kinlode ti won ma nfi panpe ofin mun awon apaniyan, gbogbo awon ti won ti fi ofin mun ko si nkankan ti won ma nse fun won, wo ma pada tu won sile ni

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 4 дня назад

    Igbati won ti dana iban bo awon ti won lo bawon ninu igbo, nse ni oye ki awon na da ibon yen pada si won ni, eni keni ti oba ti pa eniyan oye ki won mapa awon na kiakia ni, bibeko nse ni won atun mapo si ni

  • @azeezrasheed
    @azeezrasheed 3 дня назад

    Won o ni bo n be